ÌFÉ ATANTAN (TWISTED LOVE) by Haastrup Adesanmi

Credit: Stocksy
Credit: Stocksy

Òrí átàn ni mo tín ké tan tan

Tan tan, ohùn mi jákè, o já!, kán -kán

Bi ohún adìye tàn tòbe bò lórùn

Bán sokú ìfé, bán dárò ekún arewá

Eni tí yò dúró tini òní fini sìlè lo síwín lòrí atàn

 

Igi atatan ñ tani

Óní ka má to õhun dé õkè

Òkè ñ séni léyìn bútú

Ówí págbà ñ be lókè, tí ò le sòkalè

Bómodé bá fojú digi atan elérù, á dá lésè

Igi atatan, a lójú ewúro pò, só dèfó

Ó lójú òmòràn, afófungbé!u pó, so wón da láí móse

Alójú inú pò, fi pèlé pèlé sopó opolo

Alójú omidan pò, so ewà omidan di Kúrepè

 

Bí ìfé bá sá, òrùn rè a rùn jàtàn lo

Bí ìfé bá n sún kù, bígi atantan lèya rè ó ma rí

Igi atantan orí átàn bíi ìfé inú irà

Inú n ké dùn àsìkò,

Okàn n kúndùn òfìfo

Àti àsìkò, àti òfìfo

Ègbé paraku, eré orí aféfé.

TRANSLATION

 

On the valley of waste; i raised my voice and cry

Like a wolf, into the air, my voice attacks life blightly and sharp

I scream like a helpless chicken whose neck joys upon a moment of death

If we mourn the course of love and we eulogize the lose of the beautiful

Before the wrath of waste, he who would remain would remain

 

The capricious twisted tree brightens!

Never climb my twisted back, it muffles

Cos only at the top does the spine break

A home where the old graze and never return

A warning that a child ignores and loses his legs

The capricious twisted tree that twists the bitter leave into soup

Twists the brave and foolish. Bake them into the worthless

Twists the soul, and gently widows intellect

Twists the alluring, turns the damsel into a beast

 

When love fades, it stinks worse than faeces’s bunker

When love blooms, like the capricious twisted tree, it would flap its wings

The capricious twisted tree like love of the dumb

The mind again, mourns the loss of time

The heart enjoys the loss of lust

But both time and lust

Are vanity and a striving after the wind.

 

Advertisements

One Comment Add yours

  1. Programa de Reconstrução de Cabelo do Vencendo a Alopecia, é tido como uma solução para a queda
    capilar, por valer-se do conhecimento e também
    uso desses inibidores. http://schwarzealliance.de/sakoth/index.php?mod=users&action=view&id=390703

    Liked by 1 person

Leave a Reply

Fill in your details below or click an icon to log in:

WordPress.com Logo

You are commenting using your WordPress.com account. Log Out /  Change )

Google+ photo

You are commenting using your Google+ account. Log Out /  Change )

Twitter picture

You are commenting using your Twitter account. Log Out /  Change )

Facebook photo

You are commenting using your Facebook account. Log Out /  Change )

w

Connecting to %s